YORUBA-TRANSLATE ARTICLES INTO YORUBA!

Showing posts with label BLACK WOMAN. Show all posts
Showing posts with label BLACK WOMAN. Show all posts

Friday, August 7, 2015

YORUBA NEWSPAPERS!---ALAROYE-"OONI,OBA SIJUWADE LO,KO DAGBERE FENIKAN"--FROM ALAROYE NEWSPAPER,NIGERIA

FROM ALAROYE.COM


Ojo Keje Osu Kejo Odun  2015 E kaabo si ALAROYE.... iwe iroyin ti n soju omo Yoruba nibi gbogbo
::Alaroye - iwe iroyin ti n soju omo yoruba nibi gbogbo::
Nitori bawon omo egbe won se n jejo esun ipaniyan, APC pelu PDP soko oro lu ara won
Nitori bi awon omo egbe oselu APC kan se foju bale-ejo lori orisiirisii esun ipaniyan to waye nipinle Ekiti lasiko isejoba egbe naa seyin, egbe naa pelu PDP to n sejoba lowo ti n soko oro lu ara won. Gege bi APC se so, won fesun kan ijoba to wa lori aleefa,
O tan! Won ni lanloodu le egbe oselu PDP l'Ekiti
Wahala to n ba egbe oselu to n sejoba nipinle Ekiti, PDP, tun gba ona mi-in yo lojo Isegun, Tusde, ose to koja, pelu bi lanloodu to nile tegbe ohun n ya lo gege bii ile-egbe won se jawee fun won lati kuro nibe nitori airi owo ile san. Isele ohun ni ALAROYE gbo pe ko fibi kan ba awon omo egbe ohun laramu
Oro nipa Oonile, Oba Okunade Sijuwade
Nigba ti oro kan ba ti sele nile wa, paapaa laarin awa ati awon oyinbo, ohun to maa n saaba wa si okan wa, ti a o si so jade ni pe, "Awon oyinbo wo, awon oyinbo ti won ko ni asa, ti won ko mo nipa isenbaye rara." Bi a ba fee soro, tawon oyinbo ba n fi wa rerin-in, ohun ti a oo tete so naa ni pe, 'Awon apoda, nigba ti won ko ni oro-ile lodo tiwon'. Sugbon oro ko ri bee, eni ti ko ba de oko baba elomiiran ri, yoo ni ko si oko to to ti baba oun.
Moses gba jesi tuntun ni Chelsea
Ogbontagiri agbaboolu ile Naijiria to wa ni Kiloobu Chelsea, Victor Moses, ni egbe naa ti fun ni jesi ogun nomba (No. 20) bayii ki saa igbaboolu tuntun too bere. Ojo Abameta, Satide, to koja yii ni won seto awon agbaboolu
Michael Olaitan darapo mo FC Twente fungba die
Atamatase omo ile Naijiria to n se bebe fun egbe agbaboolu Olympiacos ile Greece nni, Michael Olaitan, ti darapo mo egbe agbaboolu F.C Twente orile-ede Netherlands fun igba die.



IROYIN ORISIRISI
Bose towo te fesun ijinigbe l'Ekiti toro aforiji lowo Fayose

Pako bii maalu to robe lawon afurasi ajinigbe metala kan n wo
Awon olopaa n wa a o: Ifayemi ti won fura si pe o jomo gbe lojo ikomo nipinle Ogun

Gbogbo eyin obinrin to je pe e maa n ko omo leyin lo sibi ti won ba ti n se inawo,
Nitori pe oko re ko le sere ori beedi daadaa, igbeyawo odun mejo tuka niluu Iseyin

Ile-ejo majisireeti to fikale siluu Iseyin, lagbegbe Oke-Ogun, nipinle Oyo, ti tu igbeyawo olodun mejo
Ikoko lasan ni Lanre fi n lu awon eeyan ni jibiti l'Ondo, lo ba logbon atije lasan ni

E wo o, ikoko lasan ni mo fi n lu awon eeyan ni jibiti,
Ale ni mo bi ibeji fun, ki i se oko mi—Oluremi

Pelu iyanu lawon ero kootu majisreeti kan to fikale siluu Iseyin n wo Abileko Oluremi Adesope,
Ooni: Oba Sijuwade lo, ko dagbere fenikan

Ohun ti awon araalu n reti lo sele lojo Aiku, Sannde, ijeta yii o.
Wahala be sile ninu egbe 'Osogbo Progressives Union'

Ara o rokun, bee lara o ro adie bayii laarin awon omo bibi ilu Osogbo,

Tuesday, August 24, 2010

YORUBA DICTIONARIES TO BUY!

 
 
or
Sign in to turn on 1-Click ordering.
or
Amazon Prime Free Trial required. Sign up when you check out. Learn More
Express Checkout with PayPhrase
What's this? Create PayPhrase
More Buying Choices
Have one to sell? Sell yours here
or
Get a $10.62 Amazon.com Gift Card 
A Dictionary of the Yoruba Language
 
See larger image
 

A Dictionary of the Yoruba Language [Paperback]

Nigeria University Press (Editor)
No customer reviews yet. Be the first.

List Price:$44.95
Price:$40.45 & this item ships for FREE with Super Saver ShippingDetails
You Save:$4.50 (10%)
In Stock.
Ships from and sold by Amazon.com. Gift-wrap available.
Only 4 left in stock--order soon (more on the way).
Want it delivered Thursday, August 26? 
Order it in the next 16 hours and 18 minutes, and choose One-Day Shipping at checkout. 
Details 
10 new from $40.45 7 used from $15.00
Textbook StudentJoin Amazon Student and get FREE Two-Day Shipping for one year with a free Amazon Prime membership ($79 value).

Sell This Book Back for $10.62
Whether you buy it used on Amazon for $15.00 or somewhere else, you can sell it back to our Textbook Buyback Store at the current price of $10.62Restrictions Apply
Used Price$15.00
Buyback Price$10.62
Price after
Buyback
$4.38

Special Offers and Product Promotions


Frequently Bought Together

A Dictionary of the Yoruba Language+Yoruba-English/English-Yoruba Modern Practical Dictionary+Colloquial Yoruba: The Complete Course for Beginners (Colloquial Series)
Price For All Three: $90.58
Buy the selected items together

Customers Who Bought This Item Also Bought

  Page of 8

Sponsored Content

Language Training Services

  (What's this?)
Mandarin Chinese Lessons opens new browser window
www.eChineseLearning.com    1-on-1 Online Live Lesson. Best Way To Learn. All Levels Free Trial Now
Provider: eChineseLearning (Details) | 5.0 out of 5 stars (2 reviews)

Editorial Reviews

Product Description

Based upon the nineteenth century standard work on the Yoruba language, and first ever English-Yoruba, Yoruba-English dictionary, this new edition has been revised and enlarged considerably. The dictionary contains about 50,000 references and translations; Yoruba pronunciation guidance; examples of how words are used; contemporary meanings and interpretations; and reference to grammatical usage and parts of speech. There is also an extensive list of commonly occurring birds, plants and trees, translated from Yoruba into English alongside their botanical equivalents.

Product Details


    Customers Viewing This Page May Be Interested in These Sponsored Links

      (What's this?)
         African American Books opens new browser window
      DorrancePublishing.com   -   Custom, Culture, Commentary & More by African American Authors
         Learn to Speak Igbo opens new browser window
      www.ultimatelanguagestore.com   -   Igbo course the diplomats use Learn conversational Igbo today.
         Improve your English Free opens new browser window
      www.worldenglishinstitute.org   -   Read, write, hear and speak English Prepare for TOEFL examination
    See a problem with these advertisements? Let us know

    What Do Customers Ultimately Buy After Viewing This Item?

    A Dictionary of the Yoruba Language
    45% buy the item featured on this page:
    A Dictionary of the Yoruba Language
    $40.45
    Yoruba-English/English-Yoruba Modern Practical Dictionary
    26% buy
    Yoruba-English/English-Yoruba Modern Practical Dictionary 4.0 out of 5 stars (7)
    $19.77
    Colloquial Yoruba: The Complete Course for Beginners (Colloquial Series)
    17% buy
    Colloquial Yoruba: The Complete Course for Beginners (Colloquial Series) 5.0 out of 5 stars (1)
    $30.36
    Beginner's Yoruba (Hippocrene Beginner's Series)
    7% buy
    Beginner's Yoruba (Hippocrene Beginner's Series) 3.2 out of 5 stars (4)
    $22.76

    Tags Customers Associate with This Product

     (What's this?)
    Click on a tag to find related items, discussions, and people.
      

    Sell a Digital Version of This Book in the Kindle Store

    If you are a publisher or author and hold the digital rights to a book, you can sell a digital version of it in our Kindle Store. Learn more